enter artist/album/song to search lyrics for:
Asa is really a legend of our time, simple and fascinating. Tombs up for her, cos she's da bomb.
j'adoooore ce qu'elle fais , sa voix est extra je suis tro fan ...
am a fan of Asa, i love her music, and tone. keep it real girl........
Orun, silekun i wanna have some talk, [with] you o (2xe) Nitori re mose n lola Nitori re mose n s'oge Nitori re mose n ra moto Mowole,M'obo luwa mi soro Nitori re mose wa laye Nitori re mose n woso sara Nitori re moji l'owuro Mow'aye mi lode ye A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro Nitori re mose n gbo iroyin ayo Lais'owo laisi nkankan Iya oni, layoola o B'oluwa tiwi, be naa lori Jiji moji lowuro Moji si inu ipese re Ayo at'alafia ye ye O, o o oni pe ki n ma se beru A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro Melo la fe so Melo lo si n bowa Melo la fe so, eh Melo lo si n bowa Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh Ninu iponju, Ninu idamu, b'ebi ba n p'ona mawole, maboluwa mi soro B'emi o le yan Baye ba foju dimi B'emi o le ni Mawole, maboluwa mi soro A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro Ninu iponju, Ninu idamu, b'ebi ba n p'ona mawole, maboluwa mi soro Mioni foju sunkun mo o Aye loja, oh oh...Orun..Orunile And thats fine by me....eh eh... Oh..ye ye...bring it down...oh oh..
Quote me,' Asa would me nominated for Grammy's and she s winning!!!'
Copyright 2007 © 01Lyrics.com - Contact - Link us - Privacy Policy - Contenu for webmasters